Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 14:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

bó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ọkùnrin mẹ́ta yìí wà níbẹ̀ bí mo ti wà láàyè ní Olúwa Ọlọ́run wí, wọn kò lé gba àwọn ọmọkùnrin tàbí ọmọbìnrin wọn là, ilẹ̀ náà yóò di ahoro.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 14

Wo Ísíkẹ́lì 14:16 ni o tọ