Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 14:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Tàbí bí mo bá jẹ́ kí ẹranko búburú gba orílẹ̀ èdè náà kọjá tí wọn fi sílẹ̀ láìní ọmọ tí wọ́n sì sọ di ahoro, tó bẹ́ẹ̀ tí kò sẹ́ni tó le gba ibẹ̀ kọjá torí ẹranko búburú yìí,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 14

Wo Ísíkẹ́lì 14:15 ni o tọ