Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 10:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àfiwé ojú àti ìrísí wọn rí bákan náà pẹ̀lú àwọn tí mo rí létí odò kébárì. Olúkúlùkù wọn sì ń lọ sí ọ̀kánkán tààrà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 10

Wo Ísíkẹ́lì 10:22 ni o tọ