Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 14:8-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

8. Ìwọ Éfúráímù; Kín ló tún kù tí mo ní ṣe pẹ̀lú ère òrìṣà?Èmi ó daba! lóhùn, èmi o sì ṣe ìtọ́jú rẹ.Mo dàbí igi tó ń fi gbogbo ìgbà tutù,èso tí ìwọ ń so si ń wá láti ọ̀dọ̀ mi.”

9. Ta ni ọlọgbọ́n? Òun yóò mòye àwọn nǹkan wọ̀nyíTa a ní ó mọ̀? Òun yóò ní ìmọ̀ wọn.Tí tọ́ ni ọ̀nà Olúwaàwọn olódodo si ń rìn nínú wọnṢùgbọ́n àwọn ọlọ́tẹ̀ nìyóò kọsẹ̀ nínú wọn.

Ka pipe ipin Hósíà 14