Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 14:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ènìyàn yóò tún padà gbé lábẹ́ òjijì rẹ̀.Yóò rúwé bi ọkà.Yóò sì yọ ìtànná bi àjàrà,òórùn rẹ yóò dàbí ti wáìnì Lébánónì.

Ka pipe ipin Hósíà 14

Wo Hósíà 14:7 ni o tọ