Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 14:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Yípadà ìwọ Ísírẹ́lì sí Olúwa Ọlọ́run rẹ.Ẹ̀ṣẹ̀ rẹ ló fa ìparun rẹ!

2. Ẹ gba ọ̀rọ̀ Olúwa gbọ́,Kí ẹ sì yípadà sí Olúwa.Ẹ sọ fún un pé:“Darí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wákí o sì fi oore ọ̀fẹ́ gbà wá,kí àwa kí ó lè fí ètè wa sán-an fún ọ

3. Asíríà kò le gbà wá là;A kò ní í gorí ẹsin ogunA kò sì ní tún sọ ọ́ mọ́ láé‘Àwọn ni òrìṣà wasí àwọn ohun tí ó fi ọwọ́ wa ṣe;nítorí pé lọ́dọ̀ rẹ ni àwọnaláìní baba tí ń rí àánú.’

Ka pipe ipin Hósíà 14