Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 14:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Asíríà kò le gbà wá là;A kò ní í gorí ẹsin ogunA kò sì ní tún sọ ọ́ mọ́ láé‘Àwọn ni òrìṣà wasí àwọn ohun tí ó fi ọwọ́ wa ṣe;nítorí pé lọ́dọ̀ rẹ ni àwọnaláìní baba tí ń rí àánú.’

Ka pipe ipin Hósíà 14

Wo Hósíà 14:3 ni o tọ