Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hábákúkù 2:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ègbé ni fún ẹni ti ń sọ fún igi pé, ‘Wá ṣayé?’Fún òkúta tí kò lè fọhùn pé, ‘Dìde’Ǹjẹ́ òun lè tọ́ ni sí ọ̀nà?Góòlù àti sílífa ni a fi bò ó yíká;kò sì sí èémí kan nínú rẹ

Ka pipe ipin Hábákúkù 2

Wo Hábákúkù 2:19 ni o tọ