Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hábákúkù 2:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èrè kí ni òrìṣà ni, tí oníṣọ̀nà rẹ̀ fi gbẹ́ ẹ,ère dídá àti olùkọ́ èké?Nítorí ti ẹni ti ó dá a gbẹ́kẹ̀ rẹ̀ lé ohun tí ó fúnrarẹ̀ dá;ó sì mọ ère tí kò le fọhùn.

Ka pipe ipin Hábákúkù 2

Wo Hábákúkù 2:18 ni o tọ