Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 8:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí báwo ni èmi yóò ṣe fara dàá tí èmi yóò sì rí kí ibi máa ṣubú lu àwọn ènìyàn mi? Báwo ni èmi yóò ṣe fara dàá, tí èmi yóò sì máa wo ìparun àwọn ìdíléè mi?”

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 8

Wo Ẹ́sítà 8:6 ni o tọ