Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 7:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Ṣéríṣésì sì bi Ésítà ayaba léèrè pé, “ta a ni ẹni náà? Níbo ni ẹni náà wà tí kò bẹ̀rù láti ṣe irú nǹkan bẹ́ẹ̀?”

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 7

Wo Ẹ́sítà 7:5 ni o tọ