Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 3:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ẹ mú àdàkọ kan ìwé náà kí a tẹ̀ẹ́ jáde bí òfin ní gbogbo ìgbéríko kí ó sì di mímọ̀ fún àwọn ènìyàn ìlú nítorí kí wọ́n le múra fún ọjọ́ náà.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 3

Wo Ẹ́sítà 3:14 ni o tọ