Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 3:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì fi ìwé náà ránṣẹ́ sí gbogbo àwọn ìgbèríko pẹ̀lú àṣẹ láti parun, láti pa gbogbo àwọn Júù èwe àti àgbà, obìnrin àti àwọn ọmọ wẹ́ẹ́wẹ́—ní ọjọ́ kan kí wọn sì parẹ́, ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kejìlá, oṣù Ádárì kí a sì kó àwọn ohun ìní in wọn.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 3

Wo Ẹ́sítà 3:13 ni o tọ