Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 3:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ìránṣẹ́ náà sì jáde, wọ́n tẹ̀síwájú nípa àṣẹ ọba, ìkéde náà sì jáde ní ìlé ìsọ́ ti Ṣúsà. Ọba àti Hámánì jókòó wọ́n ń mu, ṣùgbọ́n ìlú Ṣúsà wà nínú ìdààmú.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 3

Wo Ẹ́sítà 3:15 ni o tọ