Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 2:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnu ọ̀nà rẹ̀ ti wọ inú ilẹ̀;òpó rẹ̀ ni ó wó tí ó sì ti bàjẹ́.Ọba àti ọmọ ọbakùnrin rẹ̀ wà ní ìgbèkùn láàrin àwọn orílẹ̀ èdè,kò sí òfin mọ́,àwọn wòlíì rẹ̀ kò ríìran láti ọ̀dọ̀ Olúwa mọ́.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 2

Wo Ẹkún Jeremáyà 2:9 ni o tọ