Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa pinnu láti faògiri tí ó yí ọmọbìnrin Síónì ya.Ó gbé wọn sórí òṣùnwọ̀n,kò sì fa ọwọ́ rẹ̀ padà kúrò nínú ìparun wọn.Ó mú kí ilé-ìsọ́ àti odi rẹ̀ sọ̀fọ̀wọ́n ṣòfò papọ̀.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 2

Wo Ẹkún Jeremáyà 2:8 ni o tọ