Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 2:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọmọdé àti àgbà ń sùn papọ̀sínú eruku àwọn òpópó;àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin àti ọ̀dọ́mọbìnrin miti ṣègbé nípa idà.Ìwọ pa wọ́n run ní ọjọ́ ìbínú rẹ;Ìwọ pa wọ́n láìní àánú.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 2

Wo Ẹkún Jeremáyà 2:21 ni o tọ