Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 2:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wòó, Olúwa, kí o sì rò ó:Ta ni ìwọ ti fìyà jẹ bí èyíǸjẹ́ àwọn obìnrin yóò ha jẹ ọmọ wọn,àwọn ọmọ tí wọn ń se ìtọ́jú fún?Ǹjẹ́ kí a pa olórí àlùfáà àti àwọn wòlíìní ibi mímọ́ Olúwa?

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 2

Wo Ẹkún Jeremáyà 2:20 ni o tọ