Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìran àwọn wòlíì rẹjẹ́ kìkì ẹ̀tàn láìní ìwọ̀n;wọn kò sì fi ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ hàntí yóò mú ìgbèkùn kúrò fún ọ.Àwọn òrìṣà tí wọ́n fún ọjẹ́ èké àti ìsìnà.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 2

Wo Ẹkún Jeremáyà 2:14 ni o tọ