Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ ìpọ́njú àti àrìnká rẹ̀ niJérúsálẹ́mù rántí àwọn ohun ìní dáradára rẹ̀tí ó jẹ́ tirẹ̀ ní ọjọ́ pípẹ́.Nígbà tí àwọn ènìyàn rẹ̀ ṣubú sọ́wọ́ àwọn ọ̀tá,kò sì sí olùrànlọ́wọ́ fún un.Àwọn ọ̀tá rẹ̀ wò ówọ́n sì ń fi ìparun rẹ̀ ṣẹlẹ́yà.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 1

Wo Ẹkún Jeremáyà 1:7 ni o tọ