Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jérúsálẹ́mù sì ti dẹ́ṣẹ̀ púpọ̀ó sì ti di aláìmọ́.Àwọn tí ó ń tẹríba fún un sì kẹ́gàn rẹ̀,nítorí wọ́n ti rí ìhòòhò rẹ̀;ó kérora fúnra rẹ̀,ó sì lọ kúrò.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 1

Wo Ẹkún Jeremáyà 1:8 ni o tọ