Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 8:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fáráò ránṣẹ́ pe Mósè àti Árónì, ó sì sọ fún wọn pé, “Gbàdúrà sí Olúwa kí ó mú àwọn ọ̀pọ̀lọ́ wọ̀nyí kúrò lọ́dọ̀ mi àti lára àwọn ènìyàn mi, Èmi yóò sì jẹ́ kí àwọn ènìyàn rẹ kí ó lọ láti rúbọ sí Olúwa.”

Ka pipe ipin Ékísódù 8

Wo Ékísódù 8:8 ni o tọ