Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 8:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sọ fún Fáráò pé, “Jọ̀wọ́ sọ fún mi ìgbà ti èmi yóò gbàdúrà fún ọ àti àwọn ìjòyè rẹ àti fún àwọn ènìyàn rẹ, kí àwọn ọ̀pọ̀lọ́ wọ̀nyí bá lè lọ lọ́dọ̀ rẹ àti ní àwọn ilé yín tí wọn yóò sì wà nínú odò Náílì nìkan.”

Ka pipe ipin Ékísódù 8

Wo Ékísódù 8:9 ni o tọ