Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìgbà náà ni Olúwa wí pé, “Ti ọwọ́ rẹ bọ ìnú aṣọ ní igbá àyà rẹ̀.” Mósè sì ti ọwọ́ rẹ̀ bọ inú aṣọ ní igbá àyá rẹ̀, ní ìgbá ti ó sì yọ ọ́ jáde, ọwọ́ rẹ̀ ti dẹ́tẹ̀, ó sì ti funfun bí ẹ̀gbọ̀n òwú.

Ka pipe ipin Ékísódù 4

Wo Ékísódù 4:6 ni o tọ