Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 4:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì wí pé, “Èyí rí bẹ́ẹ̀ kí wọn bá à le è gbàgbọ́ pé, Olúwa Ọlọ́run àwọn baba wọn: Ọlọ́run Ábúráhámù, Ọlọ́run Ísáákì, àtì Ọlọ́run Jákọ́bù; tí farahàn ọ́.”

Ka pipe ipin Ékísódù 4

Wo Ékísódù 4:5 ni o tọ