Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 4:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì sọ fún un pé, “Ta ni ó fún ènìyàn ni ẹnu? Ta ni ó mú un ya odi tàbí adití? Ta ni ó mú un ríran, tàbí mú un fọ́jú? Ǹjẹ́ kì í ṣe Èmi Olúwa?

Ka pipe ipin Ékísódù 4

Wo Ékísódù 4:11 ni o tọ