Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì sọ fún Olúwa pé, “Èmi jẹ́ akọ́lòlò, èmi kì í ṣe ẹni tó lè sọ̀rọ̀ já gaara láti ìgbà àtijọ wá tàbí láti ìgbà ti o ti ń bá ìránṣẹ́ rẹ sọ̀rọ̀, mo jẹ́ ẹni ti ahọ́n rẹ̀ lọ́ tí ó sì ń lọ́ra àti sọ̀rọ̀.”

Ka pipe ipin Ékísódù 4

Wo Ékísódù 4:10 ni o tọ