Mósè bẹ iṣẹ́ náà wò, ó sì rí i wí pé wọ́n ti ṣe é gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pà ṣẹ. Nítorí náà Mósè sì bùkún fún wọn.