Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 36:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì pàṣẹ, wọ́n sì rán iṣẹ́ yìí sí gbogbo ibùdó: “Kí ọkùnrin tàbí obìnrin má ṣe ṣe ohun kankan bí ọrẹ fún ibi mímọ́ náà mọ́.” Bẹ́ẹ̀ ni a dá àwọn ènìyàn lẹ́kun láti mú un wá sí i,

Ka pipe ipin Ékísódù 36

Wo Ékísódù 36:6 ni o tọ