Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 26:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣo aṣọ títa náà sí ìṣàlẹ̀ àwọn ìkọ́, kí o sì gbé àpótí ẹ̀rí sí ẹ̀gbẹ́ aṣọ títa náà. Aṣọ títa náà yóò pínyà ibi mímọ́ kúrò ní ibi mímọ́ tí ó ga jùlọ.

Ka pipe ipin Ékísódù 26

Wo Ékísódù 26:33 ni o tọ