Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 26:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣe ogójì (40) ihà ìtẹ̀bọ̀ fàdákà kí ó lọ sí ìṣàlẹ̀ wọn, méjì fún pákó kọ̀ọ̀kan, ọ̀kan ní ìṣàlẹ̀ ìtẹ̀bọ̀ kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Ékísódù 26

Wo Ékísódù 26:19 ni o tọ