Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wo ìhín, ó wo ọ̀hún, nígbà tí kò rí ẹnìkankan, ni ó bá pa ará Éjíbítì náà, ó sì bò ó mọ́ inú iyanrìn.

Ka pipe ipin Ékísódù 2

Wo Ékísódù 2:12 ni o tọ