Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 12:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ ṣe àpèjẹ àkàrà aláìwú, nítorí ọjọ́ yìí ni mo mú un yín jáde ni Éjíbítì. Ẹ ṣe àjọyọ̀ ọjọ́ yìí gẹ́gẹ́ bí ìlànà tí yóò wà títí ayé ní àwọn ìran tí ń bọ̀.

Ka pipe ipin Ékísódù 12

Wo Ékísódù 12:17 ni o tọ