Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 5:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bọ̀wọ̀ fún baba àti ìyáà rẹ, bí Olúwa Ọlọ́run yín ti pàṣẹ fún un yín, kí ẹ ba à le è pẹ́ láyé, àti kí ó bá à lè dára fún un yín ní ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run yín yóò fún un yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 5

Wo Deutarónómì 5:16 ni o tọ