Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 5:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ rántí pé ẹ ti jẹ́ ẹrú ní Éjíbítì rí, àti pé Olúwa Ọlọ́run yín yọ yín kúrò níbẹ̀ pẹ̀lú agbára ńlá, àti nína ọwọ́ rẹ̀. Torí èyí ni Olúwa Ọlọ́run yín ṣe pàṣẹ fún un yín láti ya ọjọ́ ìsinmi sí mímọ́.

Ka pipe ipin Deutarónómì 5

Wo Deutarónómì 5:15 ni o tọ