Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 30:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti nígbà tí ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ bá yípadà sí Olúwa Ọlọ́run rẹ tí o sì gbọ́rọ̀ sí pẹ̀lú gbogbo àyà rẹ àti gbogbo ọkàn rẹ gẹ́gẹ́ bí gbogbo ohun tí mo ti paláṣẹ fún un yín lónìí.

Ka pipe ipin Deutarónómì 30

Wo Deutarónómì 30:2 ni o tọ