Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 30:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí gbogbo ìbùkún àti ègún wọ̀nyí tí mo ti gbé kalẹ̀ ṣíwájú u yín bá wá sórí i yín àti tí o bá mú wọn sí àyà rẹ níbikíbi tí Olúwa Ọlọ́run rẹ bá tú ọ ká sí láàrin àwọn orílẹ̀ èdè,

Ka pipe ipin Deutarónómì 30

Wo Deutarónómì 30:1 ni o tọ