Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 23:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹrú kan bá ti gba ààbò lọ́dọ̀ rẹ, má ṣe fi lé ọ̀gá rẹ̀ lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Deutarónómì 23

Wo Deutarónómì 23:15 ni o tọ