Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 2:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ gbáradì, kí ẹ sì kọjá odò Ánónì. Kíyèsi, Mo ti fi Ṣíhónì ará Ámórì, ọba Héṣíbónì àti ilẹ̀ rẹ̀ lé ọ lọ́wọ́. Ẹ bá ilẹ̀ náà jagun kí ẹ sì gbà á.

Ka pipe ipin Deutarónómì 2

Wo Deutarónómì 2:24 ni o tọ