Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 2:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi bẹ̀rẹ̀ sí ní fi ìbẹ̀rù àti ìfòyà yín sára gbogbo orílẹ̀ èdè lábẹ́ ọ̀run láti òní lọ. Wọn yóò gbọ́ ìròyìn in yín, wọn yóò sì wárìrì, wọn yóò sì wà nínú ìdàmú ọkàn torí i ti yín.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 2

Wo Deutarónómì 2:25 ni o tọ