Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 16:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ fi ẹran kan rúbọ bí ìrékọjá sí Olúwa Ọlọ́run yín láti inú ọ̀wọ́ ẹran tàbí agbo màlúù yín ní ibi tí Olúwa Ọlọ́run yín yóò yàn bí ibùgbé fún orúkọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 16

Wo Deutarónómì 16:2 ni o tọ