Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 16:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kíyèsí oṣù Ábíbù, kí ẹ sì máa ṣe àjọ̀dún ìrékọjá ti Olúwa Ọlọ́run yín, nítorí pé ní oṣù Ábíbù yìí ni ó mú un yín jáde ní Éjíbítì lóru.

Ka pipe ipin Deutarónómì 16

Wo Deutarónómì 16:1 ni o tọ