Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 9:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ti mú ọ̀rọ̀ tí o sọ sí wa sẹ àti lórí àwọn alákòóso wa, nípa mímú kí ibi ńlá bá wa, irú èyí tí kò tíì ṣẹlẹ̀ rí lábẹ́ ọ̀run, bí ó ti ṣẹlẹ̀ sí Jérúsálẹ́mù yìí.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 9

Wo Dáníẹ́lì 9:12 ni o tọ