Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 9:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí a ti kọ ọ́ sínú òfin Mósè bẹ́ẹ̀ ni gbogbo ibi yìí ti dé bá wa, ṣíbẹ̀ a kò bẹ̀bẹ̀ fún ojú rere Olúwa Ọlọ́run wa, nípa yíyí padà kí a kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ wa kí a sì mọ òtítọ́ ọ rẹ.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 9

Wo Dáníẹ́lì 9:13 ni o tọ