Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 9:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo Ísírẹ́lì ti ṣẹ̀ sí òfin rẹ, wọ́n ti yípadà kúrò ní ọ̀dọ̀ rẹ, wọ́n kọ̀ láti ṣe ìgbọràn sí ọ.“Nígbà náà ni ègún àti ìdájọ́ tí a kọ sílẹ̀ pẹ̀lú ìbúra nínú òfin Mósè ìránṣẹ́ Ọlọ́run dà sórí i wa, nítorí tí àwa ti sẹ̀ sí ọ.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 9

Wo Dáníẹ́lì 9:11 ni o tọ