Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 7:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì fi ìjọba, ògo àti agbára ilẹ̀ ọba fún un; gbogbo ènìyàn, orílẹ̀ èdè àti èdè gbogbo wọn wólẹ̀ fún un. Ìjọba rẹ̀, ìjọba ayérayé ni, èyí tí kò le è kọjá, ìjọba rẹ̀ kò sì le è díbàjẹ́ láéláé.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 7

Wo Dáníẹ́lì 7:14 ni o tọ