Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 7:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nínú ìran mi ní òru mo wò, mo rí ẹnìkan tí ó dúró sí iwájú u mi, ó rí bí ọmọ ènìyàn, ó ń bọ̀ wá nínú àwọ̀ọsánmọ̀ ọ̀run, ó ń bọ̀ wá sí ọ̀dọ̀ ẹni ìgbàanì, a sì mú u wá sí iwájú rẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 7

Wo Dáníẹ́lì 7:13 ni o tọ