Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òpin ìgbà náà, Èmi, Nebukadinéṣárì gbé ojú ù mi sókè sí ọ̀run, iyè mi sì sọjí. Mo fi ọpẹ́ fún Ọ̀ga Ògo; mo fi ọlá àti ògo fún ẹni tí ó wà láéláé.Ìjọba rẹ̀ ìjọba títí ayé niìjọba rẹ̀ wà láti ìran dé ìran

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:34 ni o tọ