Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́ṣẹ̀kẹṣẹ̀ ni ohun tí a sọ nípa Nebukadinéṣárì ṣẹlẹ̀ sí i. A lé e kúrò láàrin ènìyàn, ó sì ń jẹ koríko bí i màlúù, ìrì ọ̀run sì ń ṣẹ̀ sí ara rẹ̀, títí irun orí i rẹ̀ fi gùn bí i ti ìyẹ́ ẹyẹ idì, tí èékánná rẹ̀ sì dàbí i ti ẹyẹ.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:33 ni o tọ