Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ó lé ọ kúrò láàrin àwọn ènìyàn, ìwọ yóò sì lọ máa gbé àárin àwọn ẹranko igbó; ìwọ yóò jẹ koríko bí i màlúù, ìgbà méje yóò kọjá lórí i rẹ títí ìwọ yóò fi mọ̀ wí pé, Ọ̀gá Ògo jọba lórí ìjọba ènìyàn àti pé ó ń fi fún ẹni tí ó bá wù ú.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:32 ni o tọ